Sáàmù 136:7, 8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó dá àwọn ìmọ́lẹ̀ ńlá,+Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé. 8 Oòrùn láti máa jọba lórí ọ̀sán,+Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.
7 Ó dá àwọn ìmọ́lẹ̀ ńlá,+Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé. 8 Oòrùn láti máa jọba lórí ọ̀sán,+Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.