1 Tímótì 4:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Wọ́n ka ìgbéyàwó léèwọ̀,+ wọ́n pàṣẹ pé kí àwọn èèyàn yẹra fún àwọn oúnjẹ+ tí Ọlọ́run dá pé kí àwọn tó ní ìgbàgbọ́+ tí wọ́n sì mọ òtítọ́ tó péye máa jẹ,+ kí wọ́n sì máa dúpẹ́.
3 Wọ́n ka ìgbéyàwó léèwọ̀,+ wọ́n pàṣẹ pé kí àwọn èèyàn yẹra fún àwọn oúnjẹ+ tí Ọlọ́run dá pé kí àwọn tó ní ìgbàgbọ́+ tí wọ́n sì mọ òtítọ́ tó péye máa jẹ,+ kí wọ́n sì máa dúpẹ́.