Ẹ́kísódù 20:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 “O ò gbọ́dọ̀ pààyàn.+ Nọ́ńbà 35:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 “‘Kí ẹ tó pa ẹnikẹ́ni tó bá pa èèyàn,* àwọn èèyàn gbọ́dọ̀ jẹ́rìí sí i* pé apààyàn+ ni; àmọ́ ẹ má pa ẹnikẹ́ni* tó bá jẹ́ pé ẹnì kan péré ló jẹ́rìí+ sí i. Mátíù 26:52 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 52 Jésù wá sọ fún un pé: “Dá idà rẹ pa dà sí àyè rẹ̀,+ torí gbogbo àwọn tó bá yọ idà máa ṣègbé nípasẹ̀ idà.+
30 “‘Kí ẹ tó pa ẹnikẹ́ni tó bá pa èèyàn,* àwọn èèyàn gbọ́dọ̀ jẹ́rìí sí i* pé apààyàn+ ni; àmọ́ ẹ má pa ẹnikẹ́ni* tó bá jẹ́ pé ẹnì kan péré ló jẹ́rìí+ sí i.
52 Jésù wá sọ fún un pé: “Dá idà rẹ pa dà sí àyè rẹ̀,+ torí gbogbo àwọn tó bá yọ idà máa ṣègbé nípasẹ̀ idà.+