Jẹ́nẹ́sísì 9:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ó sì dájú pé màá rántí májẹ̀mú tí mo bá ẹ̀yin àti onírúurú ohun alààyè* dá; omi ò sì tún ní pọ̀ mọ́ débi tó fi máa kún, tó sì máa pa gbogbo ẹran ara run.+ Àìsáyà 54:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “Bí àwọn ọjọ́ Nóà ló ṣe rí sí mi.+ Bí mo ṣe búra pé omi Nóà ò ní bo ayé mọ́,+Bẹ́ẹ̀ náà ni mo búra pé mi ò ní bínú sí ọ mọ́, mi ò sì ní bá ọ wí mọ́.+
15 Ó sì dájú pé màá rántí májẹ̀mú tí mo bá ẹ̀yin àti onírúurú ohun alààyè* dá; omi ò sì tún ní pọ̀ mọ́ débi tó fi máa kún, tó sì máa pa gbogbo ẹran ara run.+
9 “Bí àwọn ọjọ́ Nóà ló ṣe rí sí mi.+ Bí mo ṣe búra pé omi Nóà ò ní bo ayé mọ́,+Bẹ́ẹ̀ náà ni mo búra pé mi ò ní bínú sí ọ mọ́, mi ò sì ní bá ọ wí mọ́.+