Jẹ́nẹ́sísì 8:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Kó onírúurú ẹran ara+ tó jẹ́ ohun alààyè jáde pẹ̀lú rẹ, àwọn ẹ̀dá tó ń fò, àwọn ẹran àti gbogbo ẹran tó ń rákò lórí ilẹ̀, kí wọ́n lè máa pọ̀ sí i* ní ayé, kí wọ́n máa bímọ, kí wọ́n sì pọ̀ ní ayé.”+
17 Kó onírúurú ẹran ara+ tó jẹ́ ohun alààyè jáde pẹ̀lú rẹ, àwọn ẹ̀dá tó ń fò, àwọn ẹran àti gbogbo ẹran tó ń rákò lórí ilẹ̀, kí wọ́n lè máa pọ̀ sí i* ní ayé, kí wọ́n máa bímọ, kí wọ́n sì pọ̀ ní ayé.”+