Ìsíkíẹ́lì 27:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ilé Tógámà+ fi ẹṣin àti àwọn ẹṣin ogun àti àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́* ṣe pàṣípààrọ̀ ọjà lọ́dọ̀ rẹ. Ìsíkíẹ́lì 38:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Gómérì àti gbogbo ọmọ ogun rẹ̀, ilé Tógámà+ láti ibi tó jìnnà jù ní àríwá, pẹ̀lú gbogbo ọmọ ogun rẹ̀; ọ̀pọ̀ èèyàn wà pẹ̀lú rẹ.+
6 Gómérì àti gbogbo ọmọ ogun rẹ̀, ilé Tógámà+ láti ibi tó jìnnà jù ní àríwá, pẹ̀lú gbogbo ọmọ ogun rẹ̀; ọ̀pọ̀ èèyàn wà pẹ̀lú rẹ.+