-
Jẹ́nẹ́sísì 50:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Àwọn ọmọ Kénáánì, tó ń gbé ilẹ̀ náà rí wọn tí wọ́n ń ṣọ̀fọ̀ ní ibi ìpakà Átádì, wọ́n sì sọ pé: “Ọ̀fọ̀ ńlá ló ṣẹ àwọn ará Íjíbítì yìí o!” Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi sọ ibẹ̀ ní Ebẹli-mísíráímù,* tó wà ní agbègbè Jọ́dánì.
-