Nọ́ńbà 34:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Fi ìtọ́ni yìí tó àwọn ọmọ Ísírẹ́lì létí pé, ‘Tí ẹ bá wọ ilẹ̀ Kénáánì,+ ilẹ̀ tó máa di tiyín nìyí láwọn ibi tí ààlà+ rẹ̀ dé. 1 Kíróníkà 1:8-10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àwọn ọmọ Hámù ni Kúṣì,+ Mísíráímù, Pútì àti Kénáánì.+ 9 Àwọn ọmọ Kúṣì ni Sébà,+ Háfílà, Sábítà, Ráámà+ àti Sábítékà. Àwọn ọmọ Ráámà sì ni Ṣébà àti Dédánì.+ 10 Kúṣì bí Nímírọ́dù.+ Òun ló kọ́kọ́ di alágbára ní ayé.
2 “Fi ìtọ́ni yìí tó àwọn ọmọ Ísírẹ́lì létí pé, ‘Tí ẹ bá wọ ilẹ̀ Kénáánì,+ ilẹ̀ tó máa di tiyín nìyí láwọn ibi tí ààlà+ rẹ̀ dé.
8 Àwọn ọmọ Hámù ni Kúṣì,+ Mísíráímù, Pútì àti Kénáánì.+ 9 Àwọn ọmọ Kúṣì ni Sébà,+ Háfílà, Sábítà, Ráámà+ àti Sábítékà. Àwọn ọmọ Ráámà sì ni Ṣébà àti Dédánì.+ 10 Kúṣì bí Nímírọ́dù.+ Òun ló kọ́kọ́ di alágbára ní ayé.