Jónà 3:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Torí náà, Jónà gbéra, ó sì lọ sí Nínéfè,+ bí Jèhófà ṣe sọ fún un.+ Ìlú Nínéfè tóbi gan-an,* ọjọ́ mẹ́ta ló máa ń gbà láti rìn yí i ká. Mátíù 12:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Àwọn ará Nínéfè máa dìde láti ṣèdájọ́ ìran yìí, wọ́n á sì dá a lẹ́bi, torí pé wọ́n ronú pìwà dà nígbà tí Jónà wàásù fún wọn.+ Àmọ́ ẹ wò ó! ohun kan tó ju Jónà lọ wà níbí.+
3 Torí náà, Jónà gbéra, ó sì lọ sí Nínéfè,+ bí Jèhófà ṣe sọ fún un.+ Ìlú Nínéfè tóbi gan-an,* ọjọ́ mẹ́ta ló máa ń gbà láti rìn yí i ká.
41 Àwọn ará Nínéfè máa dìde láti ṣèdájọ́ ìran yìí, wọ́n á sì dá a lẹ́bi, torí pé wọ́n ronú pìwà dà nígbà tí Jónà wàásù fún wọn.+ Àmọ́ ẹ wò ó! ohun kan tó ju Jónà lọ wà níbí.+