ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 25:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 ilẹ̀ tí Ábúráhámù rà lọ́wọ́ àwọn ọmọ Hétì. Ibẹ̀ ni wọ́n sin Ábúráhámù sí, pẹ̀lú Sérà+ ìyàwó rẹ̀.

  • Jẹ́nẹ́sísì 27:46
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 46 Lẹ́yìn ìyẹn, Rèbékà ń tẹnu mọ́ ọn fún Ísákì pé: “Àwọn ọmọbìnrin Hétì+ ti fayé sú mi. Bí Jékọ́bù bá lọ fẹ́ ìyàwó nínú àwọn ọmọ Hétì, irú àwọn ọmọbìnrin ilẹ̀ yìí, kí làǹfààní pé mo wà láàyè?”+

  • 1 Kíróníkà 1:13-16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Kénáánì bí Sídónì+ àkọ́bí rẹ̀ àti Hétì+ 14 àti àwọn ará Jébúsì,+ àwọn Ámórì,+ àwọn Gẹ́gáṣì,+ 15 àwọn Hífì,+ àwọn Ákì, àwọn Sáínì, 16 àwọn ọmọ Áfádì,+ àwọn Sémárì àti àwọn ará Hámátì.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́