-
Ìsíkíẹ́lì 27:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Àwọn ará Áfádì tó wà lára àwọn ọmọ ogun rẹ wà lórí ògiri rẹ yí ká,
Àwọn ọkùnrin onígboyà sì wà nínú àwọn ilé gogoro rẹ.
Wọ́n gbé àwọn apata* wọn kọ́ sára ògiri rẹ yí ká,
Wọ́n sì buyì kún ẹwà rẹ.
-