Jóṣúà 15:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Èyí ni ogún ẹ̀yà Júdà ní ìdílé-ìdílé. Jóṣúà 15:47 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 47 Áṣídódì,+ àwọn àrọko rẹ̀* àti àwọn ìgbèríko rẹ̀; Gásà,+ àwọn àrọko rẹ̀ àti àwọn ìgbèríko rẹ̀, dé Àfonífojì Íjíbítì àti Òkun Ńlá* pẹ̀lú ibi tó wà ní ẹ̀gbẹ́ rẹ̀.+ Ìṣe 8:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Àmọ́, áńgẹ́lì Jèhófà*+ bá Fílípì sọ̀rọ̀, ó ní: “Dìde kí o sì lọ sí gúúsù ní ọ̀nà tó lọ láti Jerúsálẹ́mù sí Gásà.” (Èyí jẹ́ ọ̀nà aṣálẹ̀.)
47 Áṣídódì,+ àwọn àrọko rẹ̀* àti àwọn ìgbèríko rẹ̀; Gásà,+ àwọn àrọko rẹ̀ àti àwọn ìgbèríko rẹ̀, dé Àfonífojì Íjíbítì àti Òkun Ńlá* pẹ̀lú ibi tó wà ní ẹ̀gbẹ́ rẹ̀.+
26 Àmọ́, áńgẹ́lì Jèhófà*+ bá Fílípì sọ̀rọ̀, ó ní: “Dìde kí o sì lọ sí gúúsù ní ọ̀nà tó lọ láti Jerúsálẹ́mù sí Gásà.” (Èyí jẹ́ ọ̀nà aṣálẹ̀.)