1 Kíróníkà 1:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ọmọ méjì ni Ébérì bí. Ọ̀kan ń jẹ́ Pélégì,*+ torí pé ìgbà ayé rẹ̀ ni ayé* pín sọ́tọ̀ọ̀tọ̀. Orúkọ arákùnrin rẹ̀ ni Jókítánì.
19 Ọmọ méjì ni Ébérì bí. Ọ̀kan ń jẹ́ Pélégì,*+ torí pé ìgbà ayé rẹ̀ ni ayé* pín sọ́tọ̀ọ̀tọ̀. Orúkọ arákùnrin rẹ̀ ni Jókítánì.