1 Àwọn Ọba 9:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Wọ́n lọ sí Ófírì,+ wọ́n sì kó ọgọ́rùn-ún mẹ́rin ó lé ogún (420) tálẹ́ńtì wúrà láti ibẹ̀ wá fún Ọba Sólómọ́nì. 1 Àwọn Ọba 10:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ọ̀wọ́ ọkọ̀ òkun tí Hírámù fi kó wúrà láti Ófírì+ tún kó àwọn gẹdú igi álígọ́mù+ tó pọ̀ gan-an wá àti àwọn òkúta iyebíye.+
28 Wọ́n lọ sí Ófírì,+ wọ́n sì kó ọgọ́rùn-ún mẹ́rin ó lé ogún (420) tálẹ́ńtì wúrà láti ibẹ̀ wá fún Ọba Sólómọ́nì.
11 Ọ̀wọ́ ọkọ̀ òkun tí Hírámù fi kó wúrà láti Ófírì+ tún kó àwọn gẹdú igi álígọ́mù+ tó pọ̀ gan-an wá àti àwọn òkúta iyebíye.+