Jeremáyà 50:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 50 Ọ̀rọ̀ tí Jèhófà sọ nípa Bábílónì,+ nípa ilẹ̀ àwọn ará Kálídíà, nípasẹ̀ wòlíì Jeremáyà nìyí: