Jẹ́nẹ́sísì 10:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Àwọn ọmọ Ṣémù ni Élámù,+ Áṣúrì,+ Ápákíṣádì,+ Lúdì àti Árámù.+ 1 Kíróníkà 1:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àwọn ọmọ Ṣémù ni Élámù,+ Áṣúrì,+ Ápákíṣádì, Lúdì àti Árámùàti* Úsì, Húlì, Gétérì àti Máṣì.+