Jẹ́nẹ́sísì 10:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ṣémù náà bímọ, òun ni baba ńlá gbogbo àwọn ọmọ Ébérì,+ òun sì ni arákùnrin Jáfẹ́tì tó jẹ́ ẹ̀gbọ́n pátápátá.* 1 Kíróníkà 1:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ápákíṣádì bí Ṣélà, Ṣélà+ sì bí Ébérì.
21 Ṣémù náà bímọ, òun ni baba ńlá gbogbo àwọn ọmọ Ébérì,+ òun sì ni arákùnrin Jáfẹ́tì tó jẹ́ ẹ̀gbọ́n pátápátá.*