ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 16:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Sáráì ìyàwó Ábúrámù kò bí ọmọ kankan+ fún un, àmọ́ ó ní ìránṣẹ́ kan tó jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Íjíbítì, Hágárì+ ni orúkọ rẹ̀. 2 Sáráì wá sọ fún Ábúrámù pé: “Jọ̀ọ́, gbọ́ ohun tí mo fẹ́ sọ! Jèhófà ò jẹ́ kí n bímọ. Jọ̀ọ́, bá ìránṣẹ́ mi ní àṣepọ̀. Bóyá mo lè ní ọmọ nípasẹ̀ rẹ̀.”+ Ábúrámù sì fetí sí ohun tí Sáráì sọ.

  • Róòmù 4:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ìgbàgbọ́ rẹ̀ kò yẹ̀, ó ro ti ara rẹ̀ tó ti di òkú tán (torí ó ti tó nǹkan bí ẹni ọgọ́rùn-ún [100] ọdún),+ ó tún ro ti ilé ọlẹ̀ Sérà tó ti kú.*+

  • Hébérù 11:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Ìgbàgbọ́ mú kí Sérà náà gba agbára láti lóyún ọmọ,* kódà nígbà tí ọjọ́ orí rẹ̀ ti kọjá ti ẹni tó lè bímọ,+ torí ó ka Ẹni tó ṣe ìlérí náà sí olóòótọ́.*

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́