Jẹ́nẹ́sísì 20:11, 12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ábúráhámù fèsì pé: “Èrò mi ni pé, ‘Ó dájú pé àwọn èèyàn tó wà níbí kò bẹ̀rù Ọlọ́run, wọ́n á sì pa mí torí ìyàwó+ mi.’ 12 Àbúrò mi ni lóòótọ́ o, bàbá kan náà ló bí wa, àmọ́ a kì í ṣọmọ ìyá kan náà, mo sì mú un ṣaya.+
11 Ábúráhámù fèsì pé: “Èrò mi ni pé, ‘Ó dájú pé àwọn èèyàn tó wà níbí kò bẹ̀rù Ọlọ́run, wọ́n á sì pa mí torí ìyàwó+ mi.’ 12 Àbúrò mi ni lóòótọ́ o, bàbá kan náà ló bí wa, àmọ́ a kì í ṣọmọ ìyá kan náà, mo sì mú un ṣaya.+