Nọ́ńbà 34:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Fi ìtọ́ni yìí tó àwọn ọmọ Ísírẹ́lì létí pé, ‘Tí ẹ bá wọ ilẹ̀ Kénáánì,+ ilẹ̀ tó máa di tiyín nìyí láwọn ibi tí ààlà+ rẹ̀ dé. Nọ́ńbà 34:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Kí ààlà náà lọ dé Jọ́dánì, kó sì parí sí Òkun Iyọ̀.+ Èyí ni yóò jẹ́ ilẹ̀+ yín àti àwọn ààlà rẹ̀ yí ká.’”
2 “Fi ìtọ́ni yìí tó àwọn ọmọ Ísírẹ́lì létí pé, ‘Tí ẹ bá wọ ilẹ̀ Kénáánì,+ ilẹ̀ tó máa di tiyín nìyí láwọn ibi tí ààlà+ rẹ̀ dé.
12 Kí ààlà náà lọ dé Jọ́dánì, kó sì parí sí Òkun Iyọ̀.+ Èyí ni yóò jẹ́ ilẹ̀+ yín àti àwọn ààlà rẹ̀ yí ká.’”