Diutarónómì 2:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 (Àwọn Émímù+ ló ń gbé ibẹ̀ tẹ́lẹ̀, èèyàn ńlá ni wọ́n, wọ́n pọ̀ gan-an, wọ́n sì ga bí àwọn Ánákímù. 11 Àwọn Réfáímù+ náà rí bí àwọn Ánákímù,+ àwọn ọmọ Móábù sì máa ń pè wọ́n ní Émímù.
10 (Àwọn Émímù+ ló ń gbé ibẹ̀ tẹ́lẹ̀, èèyàn ńlá ni wọ́n, wọ́n pọ̀ gan-an, wọ́n sì ga bí àwọn Ánákímù. 11 Àwọn Réfáímù+ náà rí bí àwọn Ánákímù,+ àwọn ọmọ Móábù sì máa ń pè wọ́n ní Émímù.