-
Jẹ́nẹ́sísì 14:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Ó gba gbogbo ẹrù náà pa dà, ó sì tún gba Lọ́ọ̀tì mọ̀lẹ́bí rẹ̀ àti àwọn ẹrù rẹ̀ pa dà pẹ̀lú àwọn obìnrin àti àwọn èèyàn míì.
-