Jẹ́nẹ́sísì 13:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ábúrámù sì ń gbé inú àgọ́. Nígbà tó yá, ó lọ ń gbé láàárín àwọn igi ńlá Mámúrè,+ tó wà ní Hébúrónì;+ ó sì mọ pẹpẹ kan síbẹ̀ fún Jèhófà.+
18 Ábúrámù sì ń gbé inú àgọ́. Nígbà tó yá, ó lọ ń gbé láàárín àwọn igi ńlá Mámúrè,+ tó wà ní Hébúrónì;+ ó sì mọ pẹpẹ kan síbẹ̀ fún Jèhófà.+