Nehemáyà 9:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 “Ìwọ nìkan ṣoṣo ni Jèhófà;+ ìwọ lo dá ọ̀run, àní ọ̀run àwọn ọ̀run àti gbogbo ọmọ ogun wọn, ayé àti gbogbo ohun tó wà lórí rẹ̀, àwọn òkun àti gbogbo ohun tó wà nínú wọn. O pa gbogbo wọn mọ́, àwọn ọmọ ogun ọ̀run sì ń forí balẹ̀ fún ọ. Sáàmù 146:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Aṣẹ̀dá ọ̀run àti ayé,Òkun àti gbogbo ohun tó wà nínú wọn,+Ẹni tó jẹ́ olóòótọ́ nígbà gbogbo,+
6 “Ìwọ nìkan ṣoṣo ni Jèhófà;+ ìwọ lo dá ọ̀run, àní ọ̀run àwọn ọ̀run àti gbogbo ọmọ ogun wọn, ayé àti gbogbo ohun tó wà lórí rẹ̀, àwọn òkun àti gbogbo ohun tó wà nínú wọn. O pa gbogbo wọn mọ́, àwọn ọmọ ogun ọ̀run sì ń forí balẹ̀ fún ọ.