Sáàmù 110:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Jèhófà ti búra, kò sì ní pèrò dà,* ó ní: “Ìwọ jẹ́ àlùfáà títí láé+Ní ọ̀nà ti Melikisédékì!”+ Hébérù 6:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 níbi tí aṣíwájú kan ti wọ̀ nítorí wa, ìyẹn Jésù,+ ẹni tó ti di àlùfáà àgbà ní ọ̀nà ti Melikisédékì títí láé.+
20 níbi tí aṣíwájú kan ti wọ̀ nítorí wa, ìyẹn Jésù,+ ẹni tó ti di àlùfáà àgbà ní ọ̀nà ti Melikisédékì títí láé.+