Róòmù 4:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Kì í ṣe nípasẹ̀ òfin ni Ábúráhámù tàbí ọmọ* rẹ̀ fi gba ìlérí pé òun ló máa jẹ́ ajogún ayé,+ àmọ́ ó jẹ́ nípasẹ̀ òdodo tó wá látinú ìgbàgbọ́.+ Róòmù 4:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nítorí náà, “a kà á sí òdodo fún un.”+ Gálátíà 3:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Gẹ́gẹ́ bí Ábúráhámù ṣe “ní ìgbàgbọ́ nínú Jèhófà,* tí a sì kà á sí òdodo fún un.”+ Jémíìsì 2:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 a sì mú ìwé mímọ́ náà ṣẹ tó sọ pé: “Ábúráhámù ní ìgbàgbọ́ nínú Jèhófà,* a sì kà á sí òdodo fún un,”+ a sì wá ń pè é ní ọ̀rẹ́ Jèhófà.*+
13 Kì í ṣe nípasẹ̀ òfin ni Ábúráhámù tàbí ọmọ* rẹ̀ fi gba ìlérí pé òun ló máa jẹ́ ajogún ayé,+ àmọ́ ó jẹ́ nípasẹ̀ òdodo tó wá látinú ìgbàgbọ́.+
23 a sì mú ìwé mímọ́ náà ṣẹ tó sọ pé: “Ábúráhámù ní ìgbàgbọ́ nínú Jèhófà,* a sì kà á sí òdodo fún un,”+ a sì wá ń pè é ní ọ̀rẹ́ Jèhófà.*+