Ẹ́kísódù 7:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àmọ́ Fáráò ò ní fetí sí yín. Ọwọ́ mi yóò tẹ Íjíbítì, màá sì fi ìdájọ́ tó rinlẹ̀ mú ogunlọ́gọ̀ mi,* ìyẹn àwọn èèyàn mi, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jáde ní ilẹ̀ náà.+ Nọ́ńbà 33:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ìgbà yẹn ni àwọn ará Íjíbítì ń sin àwọn àkọ́bí wọn+ tí Jèhófà pa torí Jèhófà ti dá àwọn ọlọ́run+ wọn lẹ́jọ́.
4 Àmọ́ Fáráò ò ní fetí sí yín. Ọwọ́ mi yóò tẹ Íjíbítì, màá sì fi ìdájọ́ tó rinlẹ̀ mú ogunlọ́gọ̀ mi,* ìyẹn àwọn èèyàn mi, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jáde ní ilẹ̀ náà.+
4 Ìgbà yẹn ni àwọn ará Íjíbítì ń sin àwọn àkọ́bí wọn+ tí Jèhófà pa torí Jèhófà ti dá àwọn ọlọ́run+ wọn lẹ́jọ́.