Àìsáyà 45:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Torí ohun tí Jèhófà sọ nìyí,Ẹlẹ́dàá ọ̀run,+ Ọlọ́run tòótọ́,Ẹni tó dá ayé, Aṣẹ̀dá rẹ̀ tó fìdí rẹ̀ múlẹ̀ gbọn-in,+Ẹni tí kò kàn dá a lásán,* àmọ́ tó dá a ká lè máa gbé inú rẹ̀:+ “Èmi ni Jèhófà, kò sí ẹlòmíì.
18 Torí ohun tí Jèhófà sọ nìyí,Ẹlẹ́dàá ọ̀run,+ Ọlọ́run tòótọ́,Ẹni tó dá ayé, Aṣẹ̀dá rẹ̀ tó fìdí rẹ̀ múlẹ̀ gbọn-in,+Ẹni tí kò kàn dá a lásán,* àmọ́ tó dá a ká lè máa gbé inú rẹ̀:+ “Èmi ni Jèhófà, kò sí ẹlòmíì.