1 Àwọn Ọba 21:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ó hùwà ìríra tó burú jáì, torí ó tẹ̀ lé àwọn òrìṣà ẹ̀gbin,* bí gbogbo àwọn Ámórì ti ṣe, àwọn tí Jèhófà lé jáde kúrò níwájú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.’”+ 2 Àwọn Ọba 21:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “Mánásè ọba Júdà ṣe gbogbo àwọn ohun ìríra yìí; ó ṣe ohun tó burú ju ti gbogbo àwọn Ámórì+ tó wà ṣáájú rẹ̀,+ ó sì fi àwọn òrìṣà ẹ̀gbin* rẹ̀ mú Júdà dẹ́ṣẹ̀.
26 Ó hùwà ìríra tó burú jáì, torí ó tẹ̀ lé àwọn òrìṣà ẹ̀gbin,* bí gbogbo àwọn Ámórì ti ṣe, àwọn tí Jèhófà lé jáde kúrò níwájú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.’”+
11 “Mánásè ọba Júdà ṣe gbogbo àwọn ohun ìríra yìí; ó ṣe ohun tó burú ju ti gbogbo àwọn Ámórì+ tó wà ṣáájú rẹ̀,+ ó sì fi àwọn òrìṣà ẹ̀gbin* rẹ̀ mú Júdà dẹ́ṣẹ̀.