Ẹ́kísódù 12:44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 44 Àmọ́ tí ẹnì kan bá ní ẹrú tó jẹ́ ọkùnrin, tó fi owó rà, kí o dádọ̀dọ́ rẹ̀.*+ Ìgbà yẹn ló tó lè jẹ nínú rẹ̀.
44 Àmọ́ tí ẹnì kan bá ní ẹrú tó jẹ́ ọkùnrin, tó fi owó rà, kí o dádọ̀dọ́ rẹ̀.*+ Ìgbà yẹn ló tó lè jẹ nínú rẹ̀.