1 Kọ́ríńtì 15:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Ìdí nìyẹn tó fi wà lákọsílẹ̀ pé: “Ádámù ọkùnrin àkọ́kọ́ di alààyè.”*+ Ádámù ìkẹyìn di ẹ̀mí tó ń fúnni ní ìyè.+ 1 Kọ́ríńtì 15:47 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 47 Ọkùnrin àkọ́kọ́ wá láti ayé, erùpẹ̀ sì ni a fi dá a;+ ọkùnrin kejì wá láti ọ̀run.+
45 Ìdí nìyẹn tó fi wà lákọsílẹ̀ pé: “Ádámù ọkùnrin àkọ́kọ́ di alààyè.”*+ Ádámù ìkẹyìn di ẹ̀mí tó ń fúnni ní ìyè.+