Jẹ́nẹ́sísì 18:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Sérà wá bẹ̀rẹ̀ sí í rẹ́rìn-ín sínú, ó ń sọ pé: “Lẹ́yìn tí mo ti gbó tán, tí olúwa mi sì ti darúgbó, ṣé mo ṣì lè nírú ayọ̀ yẹn?”+
12 Sérà wá bẹ̀rẹ̀ sí í rẹ́rìn-ín sínú, ó ń sọ pé: “Lẹ́yìn tí mo ti gbó tán, tí olúwa mi sì ti darúgbó, ṣé mo ṣì lè nírú ayọ̀ yẹn?”+