-
Jẹ́nẹ́sísì 16:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Áńgẹ́lì Jèhófà fi kún un pé: “O ti lóyún, wàá sì bí ọmọkùnrin kan, kí o pe orúkọ rẹ̀ ní Íṣímáẹ́lì,* torí Jèhófà ti gbọ́ nípa ìyà tó ń jẹ ọ́.
-