-
Jẹ́nẹ́sísì 16:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Nígbà tó yá, áńgẹ́lì Jèhófà rí i níbi ìsun omi kan nínú aginjù, ìsun omi tó wà lójú ọ̀nà Ṣúrì.+
-
-
Àwọn Onídàájọ́ 13:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Áńgẹ́lì Jèhófà ò sì fara han Mánóà àti ìyàwó rẹ̀ mọ́. Ìgbà yẹn ni Mánóà wá mọ̀ pé áńgẹ́lì Jèhófà ni.+
-