-
Jẹ́nẹ́sísì 19:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ó sọ pé: “Ẹ jọ̀ọ́, ẹ̀yin olúwa mi, ẹ jọ̀ọ́ ẹ yà sí ilé ìránṣẹ́ yín, kí ẹ sùn mọ́jú, ká sì fọ ẹsẹ̀ yín. Ẹ lè dìde ní ìdájí, kí ẹ sì máa lọ.” Wọ́n fèsì pé: “Rárá, ojúde ìlú la máa sùn mọ́jú.”
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 24:32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 Ọkùnrin náà bá wá sínú ilé, ó* tú ìjánu àwọn ràkúnmí, ó sì fún àwọn ràkúnmí náà ní pòròpórò àti oúnjẹ ẹran, ó tún fún ọkùnrin náà ní omi láti fọ ẹsẹ̀ rẹ̀ àti ẹsẹ̀ àwọn ọkùnrin tí wọ́n jọ wá.
-