Jẹ́nẹ́sísì 17:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ọlọ́run wá sọ fún Ábúráhámù pé: “Ní ti Sáráì*+ ìyàwó rẹ, má pè é ní Sáráì mọ́, torí Sérà* ni yóò máa jẹ́.
15 Ọlọ́run wá sọ fún Ábúráhámù pé: “Ní ti Sáráì*+ ìyàwó rẹ, má pè é ní Sáráì mọ́, torí Sérà* ni yóò máa jẹ́.