Róòmù 4:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ìgbàgbọ́ rẹ̀ kò yẹ̀, ó ro ti ara rẹ̀ tó ti di òkú tán (torí ó ti tó nǹkan bí ẹni ọgọ́rùn-ún [100] ọdún),+ ó tún ro ti ilé ọlẹ̀ Sérà tó ti kú.*+
19 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ìgbàgbọ́ rẹ̀ kò yẹ̀, ó ro ti ara rẹ̀ tó ti di òkú tán (torí ó ti tó nǹkan bí ẹni ọgọ́rùn-ún [100] ọdún),+ ó tún ro ti ilé ọlẹ̀ Sérà tó ti kú.*+