-
Àwọn Onídàájọ́ 19:23, 24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Ni onílé bá jáde lọ sọ fún wọn pé: “Rárá o, ẹ̀yin arákùnrin mi, ẹ má hùwà burúkú. Ẹ jọ̀ọ́, àlejò ni ọkùnrin tó wà nínú ilé mi yìí. Ẹ má hùwà tó ń tini lójú yìí. 24 Ọmọbìnrin mi tí kò tíì mọ ọkùnrin àti wáhàrì ọkùnrin náà nìyí. Ẹ jẹ́ kí n mú wọn jáde, kí ẹ sì bá wọn lò pọ̀ tó bá jẹ́ ohun tí ẹ fẹ́ nìyẹn.*+ Àmọ́ ẹ má hùwà tó ń tini lójú yìí sí ọkùnrin yìí.”
-