-
Lúùkù 17:29-31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Àmọ́ lọ́jọ́ tí Lọ́ọ̀tì kúrò ní Sódómù, òjò iná àti imí ọjọ́ rọ̀ láti ọ̀run, ó sì pa gbogbo wọn run.+ 30 Bẹ́ẹ̀ náà ló máa rí ní ọjọ́ tí a bá ṣí Ọmọ èèyàn payá.+
31 “Ní ọjọ́ yẹn, kí ẹni tó wà lórí ilé, àmọ́ tí àwọn ohun ìní rẹ̀ wà nínú ilé má sọ̀ kalẹ̀ wá kó o, bákan náà, ẹni tó bá wà nínú pápá ò gbọ́dọ̀ pa dà sí àwọn ohun tó wà lẹ́yìn.
-