Sáàmù 143:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jèhófà, jọ̀wọ́ jẹ́ kí n máa wà láàyè nítorí orúkọ rẹ. Gbà mí* nínú wàhálà nítorí òdodo rẹ.+