Jẹ́nẹ́sísì 19:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Bí wọ́n ṣe mú wọn dé ẹ̀yìn odi, ó sọ pé: “Ẹ sá àsálà fún ẹ̀mí* yín! Ẹ má wo ẹ̀yìn,+ ẹ má sì dúró níbikíbi ní agbègbè yìí!+ Ẹ sá lọ sí agbègbè olókè kí ẹ má bàa pa run!”
17 Bí wọ́n ṣe mú wọn dé ẹ̀yìn odi, ó sọ pé: “Ẹ sá àsálà fún ẹ̀mí* yín! Ẹ má wo ẹ̀yìn,+ ẹ má sì dúró níbikíbi ní agbègbè yìí!+ Ẹ sá lọ sí agbègbè olókè kí ẹ má bàa pa run!”