Sáàmù 105:14, 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Kò gbà kí ẹnikẹ́ni ni wọ́n lára,+Ṣùgbọ́n nítorí wọn, ó bá àwọn ọba wí,+15 Ó ní, “Ẹ má fọwọ́ kan àwọn ẹni àmì òróró mi,Ẹ má sì ṣe ohun búburú sí àwọn wòlíì mi.”+
14 Kò gbà kí ẹnikẹ́ni ni wọ́n lára,+Ṣùgbọ́n nítorí wọn, ó bá àwọn ọba wí,+15 Ó ní, “Ẹ má fọwọ́ kan àwọn ẹni àmì òróró mi,Ẹ má sì ṣe ohun búburú sí àwọn wòlíì mi.”+