Jẹ́nẹ́sísì 20:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ábúráhámù tún sọ nípa Sérà ìyàwó rẹ̀ pé: “Àbúrò mi ni.”+ Ni Ábímélékì ọba Gérárì bá ránṣẹ́ pe Sérà, ó sì mú un sọ́dọ̀.+ Jẹ́nẹ́sísì 20:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àbúrò mi ni lóòótọ́ o, bàbá kan náà ló bí wa, àmọ́ a kì í ṣọmọ ìyá kan náà, mo sì mú un ṣaya.+
2 Ábúráhámù tún sọ nípa Sérà ìyàwó rẹ̀ pé: “Àbúrò mi ni.”+ Ni Ábímélékì ọba Gérárì bá ránṣẹ́ pe Sérà, ó sì mú un sọ́dọ̀.+