Hébérù 11:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ìgbàgbọ́ mú kí Sérà náà gba agbára láti lóyún ọmọ,* kódà nígbà tí ọjọ́ orí rẹ̀ ti kọjá ti ẹni tó lè bímọ,+ torí ó ka Ẹni tó ṣe ìlérí náà sí olóòótọ́.*
11 Ìgbàgbọ́ mú kí Sérà náà gba agbára láti lóyún ọmọ,* kódà nígbà tí ọjọ́ orí rẹ̀ ti kọjá ti ẹni tó lè bímọ,+ torí ó ka Ẹni tó ṣe ìlérí náà sí olóòótọ́.*