-
Jẹ́nẹ́sísì 15:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ábúrámù fèsì pé: “Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ, kí lo máa fún mi, bí o ṣe rí i pé mi ò tíì bímọ, tó sì jẹ́ pé Élíésérì,+ ọkùnrin ará Damásíkù ni yóò jogún ilé mi?”
-
-
Gálátíà 4:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Síbẹ̀, kí ni ìwé mímọ́ sọ? “Lé ìránṣẹ́bìnrin náà àti ọmọkùnrin rẹ̀ jáde, nítorí ọmọ ìránṣẹ́bìnrin náà kò ní bá ọmọ obìnrin tó lómìnira pín ogún lọ́nàkọnà.”+
-