Jẹ́nẹ́sísì 17:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ọlọ́run fèsì pé: “Ó dájú pé Sérà ìyàwó rẹ máa bí ọmọkùnrin kan fún ọ, kí o sì sọ ọ́ ní Ísákì.*+ Màá sì fìdí májẹ̀mú mi tí mo bá a dá múlẹ̀, ó máa jẹ́ májẹ̀mú ayérayé fún àtọmọdọ́mọ* rẹ̀.+ Róòmù 9:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Bẹ́ẹ̀ ni kì í ṣe torí pé wọ́n jẹ́ ọmọ* Ábúráhámù+ ni gbogbo wọn fi jẹ́ ọmọ; kàkà bẹ́ẹ̀, “Látọ̀dọ̀ Ísákì ni ọmọ* rẹ yóò ti wá.”+ Hébérù 11:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 bó tiẹ̀ jẹ́ pé a ti sọ fún un pé: “Látọ̀dọ̀ Ísákì+ ni ọmọ* rẹ yóò ti wá.”
19 Ọlọ́run fèsì pé: “Ó dájú pé Sérà ìyàwó rẹ máa bí ọmọkùnrin kan fún ọ, kí o sì sọ ọ́ ní Ísákì.*+ Màá sì fìdí májẹ̀mú mi tí mo bá a dá múlẹ̀, ó máa jẹ́ májẹ̀mú ayérayé fún àtọmọdọ́mọ* rẹ̀.+
7 Bẹ́ẹ̀ ni kì í ṣe torí pé wọ́n jẹ́ ọmọ* Ábúráhámù+ ni gbogbo wọn fi jẹ́ ọmọ; kàkà bẹ́ẹ̀, “Látọ̀dọ̀ Ísákì ni ọmọ* rẹ yóò ti wá.”+