ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 20:17, 18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Ábúráhámù bẹ̀rẹ̀ sí í rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí Ọlọ́run tòótọ́, Ọlọ́run sì mú Ábímélékì àti ìyàwó rẹ̀ lára dá, pẹ̀lú àwọn ẹrúbìnrin rẹ̀, wọ́n sì wá ń bímọ; 18 nítorí Jèhófà ti mú kí gbogbo obìnrin ilé Ábímélékì di àgàn* torí Sérà, ìyàwó+ Ábúráhámù.

  • Jẹ́nẹ́sísì 26:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Lẹ́yìn náà, Ábímélékì wá sọ́dọ̀ rẹ̀ láti Gérárì pẹ̀lú Áhúsátì agbani-nímọ̀ràn rẹ̀ àti Fíkólì olórí àwọn ọmọ ogun+ rẹ̀.

  • Jẹ́nẹ́sísì 26:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Wọ́n fèsì pé: “Ó ti hàn kedere sí wa pé Jèhófà wà pẹ̀lú rẹ.+ Torí rẹ̀ la ṣe sọ pé, ‘Jọ̀ọ́, jẹ́ ká jọ búra, ká sì bá ọ+ dá májẹ̀mú

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́