Jẹ́nẹ́sísì 26:32, 33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ní ọjọ́ yẹn, àwọn ìránṣẹ́ Ísákì wá ròyìn fún un nípa kànga tí wọ́n gbẹ́,+ wọ́n sì sọ fún un pé: “A ti kan omi!” 33 Torí náà, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Ṣíbà. Ìdí nìyẹn tí orúkọ ìlú náà fi ń jẹ́ Bíá-ṣébà+ títí dòní.
32 Ní ọjọ́ yẹn, àwọn ìránṣẹ́ Ísákì wá ròyìn fún un nípa kànga tí wọ́n gbẹ́,+ wọ́n sì sọ fún un pé: “A ti kan omi!” 33 Torí náà, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Ṣíbà. Ìdí nìyẹn tí orúkọ ìlú náà fi ń jẹ́ Bíá-ṣébà+ títí dòní.