Hébérù 6:13, 14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Torí nígbà tí Ọlọ́run ṣe ìlérí fún Ábúráhámù, ó fi ara rẹ̀ búra, nígbà tó jẹ́ pé kò sí ẹlòmíì tó tóbi jù ú lọ tó lè fi búra,+ 14 ó sọ pé: “Ó dájú pé màá bù kún ọ, ó sì dájú pé màá mú kí o di púpọ̀.”+
13 Torí nígbà tí Ọlọ́run ṣe ìlérí fún Ábúráhámù, ó fi ara rẹ̀ búra, nígbà tó jẹ́ pé kò sí ẹlòmíì tó tóbi jù ú lọ tó lè fi búra,+ 14 ó sọ pé: “Ó dájú pé màá bù kún ọ, ó sì dájú pé màá mú kí o di púpọ̀.”+