-
Jẹ́nẹ́sísì 23:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 “Olúwa mi, fetí sí mi. Ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (400) ṣékélì* fàdákà ni ilẹ̀ yìí jẹ́, àmọ́ kí ni ìyẹn já mọ́ láàárín èmi àti ìwọ? Torí náà, lọ sin òkú ìyàwó rẹ.”
-